Emi ọmọ oro I no fit pass my lane Wọn ni ki n ma jade But wọn le mi Emi ọmọ owo I no do pass myself Wọn ni ki n ma sare But wọn le mi So I cannot see my brother Ojo And popo them don lock my brother up o Say make them free my brothers oh-oh Them no kill person Them be ọmọ owo o Aje ogugulusọ o Haaa o kuku ni sọ fun mi Haaa o kuku ni sọ fun mi Mo mọ pe o kuku ni sọ fun mi Gbogbo owo ti mo na Fun ọjọ meje Mo wẹṣẹ dudu K'ọjọ to lọ o Gbogbo owo ti mo na Fun ọjọ meje Mo wẹṣẹ dudu Ọjọ le lọ o Ah ki iku ma pa alanu mi Kọta mi le riran wo Kọta mi le riran wo Ah ki iku ma pa alanu wa Kọta wa le riran wo Kọta wa le riran wo Ah ki iku ma pa alanu mi Kọta mi le riran wo Kọta mi le riran wo Ah ki iku ma pa alanu wa Kọta wa le riran wo Kọta wa le riran wo I've been thinking I've been too deep in my feelings Bless my pocket Ṣe mi lọmọ t'ọn ma ji ri If I no hustle Who go take care of my siblings If I no hustle Who go take care of my siblings Mo sare wọ Jerusalem Mo gbadura ki n le pawo If ọlọpaa no lock Ojo up My brother he dey yawo Man make man kala Ẹjẹ loju mi Man make man kala ah Ẹjẹ lo u mi Gbogbo owo ti mo na Fun ọjọ meje Mo wẹṣẹ dudu K'ọjọ to lọ o Gbogbo owo ti mo na Fun ọjọ meje Mo wẹṣẹ dudu Ọjọ le lọ o Ah ki iku ma pa alanu mi Kọta mi le riran wo Kọta mi le riran wo Ah ki iku ma pa alanu wa Kọta wa le riran wo Kọta wa le riran wo