Ọmọ mi ọ̀wọ́n Bàbá rẹ ò gbọ̀n tóó Dáríjì mí o Ọmọ mi ọ̀wọ́n Ọmọ mi ọ̀wọ́n Kò sẹnì gbọn jù Ọlọ́run lọ Ṣé bó ti mọ Ó ma tó ò Ọmọ mi ọ̀wọ́n Òrìṣà òkè Oh, eh, Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Òrìṣà òkè Ọmọ mi ọ̀wọ́n Ọlú ọ̀run gan-an ò gbọ́n tó Kò sí bo ṣe ṣe tó ma t'ènìyàn Ọmọ mi ọ̀wọ́n Ọmọ mi ọ̀wọ́n Kò s'ẹ́ni gbọ́n ju Ọlú ọ̀run lọ Ṣe bó ti mọ Ó ma tó ò Ọmọ mi ọ̀wọ́n Bò n là kàkà Àwọn alaálè Wọn ò ní f'orí j'ọ̀ṣíká A ò ṣè kà A ò parọ́ A ò parọ́ o Ah, a ma là A ma là A ma là