Aleluya méje méje Oselu pé jọ f'ọjọ méje Won fẹ tó'lú lójó méje Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese Aleluya méje méje Awon ojelu ferege Won l'awọn ọmọ yepa tún ti de Wọn fẹ dá'lúrú m'èrè lè Aleluya méje méje Akonileru wọn tún ti de Wọn fẹ sọ bo'ṣè má máa gbe Iwo f'okun s'ọrun òun ṣiṣẹ agbe Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese Wọn l'awọn omidan ló m'àiyé lè Wọn fe jeka, wọn fẹ roso Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè B'oko waju si e k'ota Bo ba k'eyin si e k'ota Bo ba kú 'wọ nìkàn se ohun olese Ma gbàgbé ibí o ti n'babọ' o B'oko waju si e k'ota Bo ba k'ẹyin si e k'ota Bo ba kuwo nìkàn se ohun olese Ma gbàgbé ibí o ti n'babọ' o Aleluya méje méje (Arere epa epa) Adaleru won tun ti de (Arere epa epa) Kofe k'ọmọ o mo bàbá rẹ (Arere epa epa) Kofe k'ọkọ o gbọ t'àyà rẹ (Arere epa epa) Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese (Arere epa epa) Won l'awọn omidan lomayele (Arere epa epa) Wọn fe jeka wọn fẹ roso (Arere epa epa) Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè (Arere epa epa) Eh ya yah ya...