O ti pọ gan-an Gan-an, gan-an, gan-an Ẹ ma fi agilinti wọbọ o, kẹ ma fi were we mi Ẹni ba lọ lo le mọ a bọ le ṣalaye ni Awọn ọmọ better ti pọ Keep your money to ba n bọ Lokeloke la ma lọ, ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ Baby wa uhn uhn, mi o raye k'eeyan fẹran kan jẹun Oje lo jẹ uhn uhn, ko n ṣe iwọ nikan ẹgbẹẹgbẹrun Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju Ye, is a mental O lowo o lọ n loyun Ah sukerike rike bumbum Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan Super extravagance lọmọ Emi l'Asake medo t'ọn sọ Baby you catch my feelings ahn ahn I'm getting bigger You dey shack my head like gbana This your booty are you from Ghana? Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza Ọmọ olo mi ye ma gaza No pressure, wọn da mọ ọga Ade ẹni lọ lo bọ Wọ America lọ fun tour Akata wọn pọ lọpọ Plenty plenty ọmọge Wọn fẹ jẹ ki n sa nile Ori mi lo yọ mi, ọta I ba yọ mi Ọmọ ọpẹ I dey find my way Make bad belle no come stop my reign Bẹbẹ n lọ like a moving train Fun mi ni big big money no chicken change Owo n bọ, ọla n bọ, alaafia ati igbadun n bọ I no wan talk plenty talk my record can back it up La-do-re-mi-fa-mi-so-la (L'Eko) Oluwa ni ṣọla Yarinya Haba! Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju Ye, is a mental O lowo o lọ n loyun Ah sukerike rike bumbum Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan Super extravagance lọmọ Emi l'Asake medo t'ọn sọ Baby you catch my feelings ahn ahn I'm getting bigger You dey shack my head like gbana This your booty are you from Ghana? Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya, ma ṣe jẹ k'ọn mọ This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza Ọmọ olo mi ye ma gaza Mr Money, Money dance, Mr Money Money dance, Mr Money, Money dance Mr Money, Money dance, Mr Money Money dance, Mr Money, Money dance Mr Money, Money dance, Mr Money Money dance