Oru sẹ ileku, I wanna have some talk, with you-o Nitori rẹ mo sẹ lola Nitori rẹ mo sẹ sogẹ Nitori rẹ mo sẹ ra moto Mo wo lẹ, mo boluwa mi soro Nitori rẹ mo sẹ wa laiye Nitori rẹ mo sẹ wa so sara Nitori re moji lowuro Mo wo aye mi lo de ye ya Aa aho ha ha a ha Iba fi ele iba fi eledua Aa ho ho a ho Mo mo le ye mo boluwa mi soro Nitori re mo sẹ gbo Iroyin ayo lai so owo lai si nkan kan I ya oni layo la o o boluwa se wi be na lori Oh oh o wi kpe kim ma se beru So aho ho a ho a a ho Aa aho ha ha a ha Iba fi ele iba fun eledua mo wo le mo boluwa mi soro Ninu ikpon ju Ninu i damu be emi ba gbo ro ma wo lẹ ma boluwa mi soro bẹ emi o lẹ yọ ba aye ba fi oju dẹ mi be emi oni ile ma wo le ma boluwa mi soro Aa aho ha ha a ha iba fi ele iba fun eledua iba o o o o mo wo le ye mo boluwa mi soro O o o mi Ninu ikpon ju Ninu idamu be mi ba gbo ro ma wo le ma boluwa mi soro mo o ni foju sunku mo o o o aye lo ja, orun ni ile ẹni a fi ba mi iba O O O